Àwọn Jàndùkú L’ọlọ́pa ń lò fi Ṣiṣẹ́ Nipinlẹ̀ Èkó
Awon awako lagbegbe Berger ati Oshodi nipinle Eko ni won ti n ke gbajare bayi, ti won si n soo di mimo wipe awon janduku ni awon agbofinro nlo lawon agbegbe yii lati maa gba owo lowo awon lojoojumo. Gege bi Tolulope se fi to awon oniroyin leti, o ni owo ti awon n san […]
Àwọn Mọ̀lẹ́bí Ajayi ń béèrè fún Ìdájọ́ Òdodo
Awon molebi Baba agba, eni aadorin odun 70 years, Aminu Ajayi ti o je òṣìṣẹ́ ijoba teleri ti awon jandulu kan seku pa nipinle Ogun ni won ti n beere bayi fun idajo ododo lori iku ti o pa baba ati egbon won. Iroyin soo di mimo wipe awon janduku kan lo sekolu si baba […]
Olopa ń bère fún #100, 000 owó Police Report
Okunrin kan, Oyibe Michael lo ti n ke gbajare bayi latara bi awon olopa se n beere owo ti o to egberun lona ogorun naira, #100,000 lowo re gege bi owo ti o ni lati san ki o tó lè gba ìwé pé ó fi oro tó olopa leti eyi taa mo si police report. […]
CBN Ní Òun Kò Ní Erongbà Àtẹ̀jáde Irúfẹ́ Owó Míràn Báyìí
§Ile ifowopamo apapo Ile yii, Central Bank of Nigeria (CBN) ti soo di mimo bayi pe oun ko gbero lati se afikun fun awon irufe Ipele owo ti a n na lorileede yii lodun 2024 gege bi iroyin kan se n gbee kiri. Ninu atejade kan ti eni ti o je adari leka ikansiraeni fun […]
Àwọn Ọ̀yọ́mèsì Fẹ̀hónú Hàn Lórí Àpèrè Aláàfin
Opolopo awon omo bibi ilu Ọ̀yọ́ lọ́jọ́ Iṣẹ́gun tó kọjá ni won ti n fehonu han ni woorowo leyi to mu ki won lo duro si enu ona abawole Ile ejo giga ti Ọ̀yọ́ to wa nilu Awe latari bi ijoba ipinle Ọ̀yo ati awon Ọ̀yomesi ṣe n fi oro yiyan Alaafin tuntun fale. Ninu […]
Gómìnà Sanwo-Olu Towo Boọ Ìwé Àdéhùn Tuntun
Gomina ipinle Eko, Babajide Sanwo-Olu niroyin fi lede pe o ti towo bo iwe adehun pelu awon banki meji taa mo si African Export and import Bank pelu Access Bank lati maa ṣe akoyawo awon ise akanse fun idagbasoke ipinle Eko. Iwe adehun yii ni won buwolu nibi ipade apero awon onisowo agbaye fun ti […]
Tinubu tí dá sí Rògbòdìyàn Ìpínlẹ̀ Rivers
Aare Bola Ahmed Tinubu niroyin soo di mimo bayi pe o ti da si rogbodiyon to n lo lowo bayi nipinle Rivers laarin Gomina Siminelayi fubara ati Nyesom Wike to sese kuro lori aga gomina nibe, to ti wa di minista fun olu ilu Ile wa Abuja bayi. Iroyin fi to wa leti pe ibasepo […]
McPherson University VC Urges Federal Government To Stay Neutral In Israel And Hamas Conflict.
By Abioye Ayomide (SIWES student, West Land Poly) The Vice-Chancellor of McPherson University, Ajebo, Ogun State, Francis Igbasan, called upon the Federal Government to maintain a neutral stance in the ongoing Israel-Palestine conflict due to the diverse nature of Nigeria. Igbasan made this appeal during a conference organized by the National Association for Christian Studies […]
Blaze Consumes Ladipo Plank Market In Lagos.
Abioye Ayomide, a SIWES student (Westland POLYTECHNIC). A devastating fire that broke out in the well-known Ladipo Plank Market in Amukoko, along Iganmu Road, Orile, Lagos State. Dr. Femi Oke-Osanyitolu, the Permanent Secretary of the Lagos State Emergency Management Authority (LASEMA), confirmed that while the inferno caused extensive damage to goods and property worth millions […]
Ààrẹ Bọ́lá Tinúbú Àti Gómìnà Ẹgbẹ́ Ọ̀ṣèlú PDP Ti Dáwọ́ Ìyọnípò Fubara Dúró, Agbófinró Mún Àwọn Olùfẹ̀hónún Hàn
Ààrẹ Bọ́lá Tinúbú Àti àwọn gómìnà ẹgbẹ́ òṣèlú PDP lọ́jọ́ ìṣẹ́gun Tuesday ti gbé ìgbé sẹ̀ láti Dáwọ́ Ìyọnípò gómìnà Ìpínlẹ̀ Rivers siminalayi Fubara Dúró, Ààrẹ ṣe ìpàdé pẹ̀lú Gómìnà náà àti Ọ̀gá rẹ̀, tó kúrò lórí àlééfà tó tún jẹ́ mínísítà olú ìlú wa Àbújá, Nyesom Wike, nílé ìjọba ní Àbújá, Gómìnà Ìpínlẹ̀ Bouchi, […]