Ile Ejo Giga Ti O Kale Si Ilu Ogbomosho Ti Wogile Iyansipo Oba Ghandi Olaoye (Iroyin Awujo wa) Thursday,26th October,2023
Ile ejo giga to Fi ikale si ilu Ogbomosho ni ipinle Oyo lana ojoru ti wogile iyansipo oba Ghandi Olaoye gegebi soun ti ilu ogbomosho. Ijoba ipinle Oyo ni won ti kede olusoaguntan Ghandi Olaoye gegebi soun ti ilu ogbomosho ni ojo kejo osu kesan odun ti a wa yii lasiko ti Omo oba […]
Awon Olugbe Ni Agbegbe Abakaliki Ni Ipinle Ebonyi Ti Ké Gbajere Sita
Awon olugbe ni agbegbe Abakaliki ni ipinle Ebonyi, ti n ké gbajare bayi latari bi awon alokolounkigbe n se Fi ojojumo yo won lenu ni agbegbe oun. Iroyin fi ye wa wipe, ojojumo ni awon jaguda Pali oun ati awon omo elegbe okunkun n fi damu awon olugbe ti o wa ni ijoba ibile […]
Ìlé Ìfowópamọ́ Àgbáyé Ṣèkìlọ̀ Lórí Ogun Tó ń lọ Lọ́wọ́ Láàárín Ísírẹ́lì àti Hamas (Ìròyìn Ìtakìjí) Thursday 26th October, 2023
ile ifowopamo agbaye ti soo di mímo bayi pe Ogun to n lo lowo lorileede isreal ati Hamas le se akoba nla-nla fun oro aje agbaye. Gege bi eni to je aare ile ifowopamo yii Ajay Banga se so lojo Ìsegun ose yii nibi ìpàdé apero kan to waye lorileede Saudi Arabia. O ni ohun […]
Ìgbìmọ̀ Alẹ́nulọ́rọ̀ ti Buwọ́lu Ẹ̀yáwó fún Iṣẹ́ Àkànṣe (Ìròyìn Ìtakìjí) Thursday 26th October, 2023
Ìgbimo àwọn alenuloro ninu isejoba apapo lorileede yii lọ́jọ́ Aje ose yìí ti buwolu ìgbésẹ̀ eyawo ti ko ni ele Lori ti o fere to bilionu meta aabo dollar $3.4 lati banki apapo agbaye (World Bank) eyi ti won fe na Lori awon eto onikoko marun otooto. Gege bi minista fun eto isuna ati isakoso […]
Ẹgbẹ́ Àwọn Oníṣòwò Gáàsì Tí D’ẹ̀bi Ọ̀wọ́ngógó rẹ̀ ru àwọn alágbàtà (Ìròyìn Àkóyawọ́) Thursday 26th October, 2023
Egbe orusowo afefe idana nile yii Nigeria Association of Liquefied Petroleum Gas Marketers ti debi owongogo to de ba eroja ohun ru awon alagbata gege awon ti o moomo n fi owo le ori eroja yii ti o mu ki o won gogo. Ẹni ti o je aare egbe yii alagba Oladapo Olatubosun lo so […]
Àwọn Àgbẹ̀ Ti Ṣe Àlàkalẹ̀ Ìṣòro Wọ́n: (Ìròyìn Àkóyawọ́) Thursday 26th October, 2023
Awon agbe lorilede yii Lana ojo Isegun ni won ti soro Lori awon isoro ti won unkoju Lori ayipada to deba oju ojo, eyin to un mu adinku ba abajade ere oko wo, ti o sin se akoba fun ere ati igbe aye won lapapo. Eyin wa Ara Abajade ipade ti egbe awon agbe yi […]
Alága Àjọ EFCC tí Pàṣẹ Pé Kí Àwọn Òṣìṣẹ́ Àjọ Náà Ṣe Alakale Dúkìá Wọn: Ìròyìn Itanilólobó, 26th October 2023
Alaga titun fun ajo tó n gbogun ti iwa ibaje ati ajebanu lorilede yii (Economic and Financial Crime Commission EFCC) ogbeni ola Olukoyede Lana Ojo isegun lo ti pase wipe ki awon osise ijoba ninu ajo oun bere sini se alakale ati ijewo awon Dukia ti won ti ni pelu ibamu Ilana ajo naa ati […]
Ẹgbẹ́ Òṣìṣẹ́ ń fi Àìdunú Hàn
Agbarijo awon egbe osise lorilede yi ti fi aidunu won han latari bi ijoba apapo se un fi Oro asoyepo to wa laarin won fale lori awon etoo ti won un bere fun lati owo ijoba eyi ti yoo le mu Ara de awon ati ara ilu lapapo latari owo Irawo ori epo ti ijoba […]
Ondo Deputy Governor Ask CJ To Ignore Probe Request
By Akinkunmi Favour Oluwajomiloju (IT student, RUN) The letter from the Ondo State House of Assembly to the Chief Judge of Ondo State, Justice Olusegun Odusola, requesting the formation of an impeachment panel for the Deputy Governor, Lucky Aiyedatiwa, has been met with opposition from Aiyedatiwa’s lawyer, Ebun-Olu Adegboruwa (SAN). In a letter addressed to […]