Gómìnà Sanwo-Olu Towo Boọ Ìwé Àdéhùn Tuntun

Gomina ipinle Eko, Babajide Sanwo-Olu  niroyin fi lede pe o ti towo bo iwe adehun pelu awon banki meji taa mo si African Export and import Bank pelu Access Bank lati maa ṣe akoyawo awon ise akanse fun idagbasoke ipinle Eko.

Iwe adehun yii ni won buwolu nibi ipade apero awon onisowo agbaye fun ti odun 2023 to waye ni Guyana. Iyen Africanbean Trade and Investment Forum 2023 .
Gomina Sanwo-Olu menuba wipe lara awon ise akanse ti Ijoba ipinle Eko fe gun le bayi ni kiko afara eleekerin si erekusu Eko taa mo si 4th Mainland Bridge, Omu Creek Project, oju ona Keji fun oko LMRT Blue line eyi ti yoo lo lati mile 2 si Okokomaiko lati le mu itesiwaju ati idagbasoke ba ipinle Eko lapapo.

Leave a Reply

Back To Top