Awon Afobaje Ni Ipinlé Oyo Ti Ro Ile Ejo Lati Da Gomina Seyi Makinde Lowoko (Iroyin Akoyawo) Friday, 27th October,2023.

Awon Afobaje ni Ilu Oyo ti won n pe ni oyo-mesi, ni won n ro ile ejo wipe ki o ba awon da Gomina ipinle Oyo Seyi Makinde lowoko, lati mayoo awon kuro bi Eniyo jiga, ninu awon tiwon fe se afihan Eniti yo je Alaafin oyo.

Awon afobaje ti won n pe ipejo oun noni Bashoru Oyo, oloye Yusuf Layinka, Laguna Oyo, oloye Wakeel Oyedepo, Akinniku Oyo, oloye Amusa Yusuf, Aare ago Bashoru, oloye Wahab Oyetunji ati Alapo Oyo, oloye Gbadebo Mufutau

Awon igbimo afobaje yii so di mimo wipe, yato si ti gomina Makinde ti n yo awon eniyan bi eni nyo jiga ni awon agbegidina miran naa tun wa bii Adajo agba ipinle Oyo ati awon Minisita labe ijoba ibile pelu awon emewa re.

Won se ni alaye wipe ni ogbon ojo osu kesan odun 2023 ni awon se ipade po ti awon si ti forikori lati yan omoba Lukmon Gbadegesin gegebi eniti o kan lati je Alaafin Oyo lori aga oba ti o ti sofo lati bi osu kerin odun 2021 tii oba Lamidi Adeyemi ti waja.

Leave a Reply

Back To Top