‘A kò gbọ́dọ̀ f’ọwọ́ yẹpẹrẹ mú idibò tó ń bọ̀ yìí. – INEC (Ìròyìn Àkóyawọ́) Friday 27th October, 2023.

Ajo olominira eto idibo nile yii, Independent National Electoral Commission (INEC) ti soo di mimo wipe eto idibo sipo gomina.eyi to n bo lona yii lojo Kokanla, osu kokanla odun yii lawon ipinle kogi, Bayelsa ati Imo,o ni eto idibo naa je eyi to se Koko ti a ko gbodo fowo yepere mu labe bo ti wu ko ri. Eni to je alaga àjò yii, Ojogbon Mahmood Yakubu lo Soro yii nibi ipade olosu meta-meta ti won maa n se fun agbeyewo akoyawo ìṣe won eyi to waye loni Ojoru nilu Abuja.

Yakubu ni ajo INEC yoo ri daju pe eto idibo naa lo ni irowo Irose, lona ti ko ni si boju-boju tabi konu-nkoho ninu ati wipe won yoo faaye gba awon alabojuto lati ile okere lati se abojuto lona to ye leyi ti orileede wa paapaa yoo fi f je amuyangan.

gan lojuna sise akoyawo eto idibo Laarin awon orileede to lenu Loro Lagbaye .

Leave a Reply

Back To Top