Ile ejo giga to fikale silu Ogbomoso nipinle Oyo ti wogile iyansipo Oba Ghandi Olaoye gege bi Soun tuntun fun ilu Ogbomoso. E o ranti pe lojo kejo osu kesan odun 2023 taa wa yii ni ijoba ipinle Oyo kede Oluso agutan Ghandi bi Soun tuntun, ṣùgbọ́n kí ó to di Igba naa ni Kabir Laoye to je okan Lara awon tó n du oye naa ti pe Ghandi lejo Leyi to so pe oye naa ko to sii. Bi o ti le je pe ile ejo ti paa lase fun ijoba ipinle, Oyo lati mase kede enikeni gege bi Soun titi di asiko ti oro ejo naa yoo fi yanju. Sigbon ti ijoba ipinle Oyo kotiikun si ikilo naa.
Adajo Adedokun ti ile ejo giga naa ti wa soo di mimo bayi, pe Iyansipo Ghandi Olaoye ko ba ofin mu bee lo pase fun awon afobaje nilu Igbomoso lati gbe igbese fun yiyan oba tuntun.