Tinubu Buwọ́lu owó tí ó tó Bilionu Méjìdínlógún fún Awọn Molebi Àwọn Akoni Tó Ti D’Olóògbé

Aare Bola Ahmed Tinubu ti buwolu owo ti o to billionu mejindinlogun naira (#18bn) fun awon ebi awon akoni to subu loju ìjà l’Ojoru tó Kọjá yìí gege bí anfani fún àwọn molebi àwọn ènìyàn náà .

Aare so wipe oun bù owo lu owo fun awon olóògbé náà ni ibamu pelu ise won ki o to di pe won padanu emi won,

Oro yi lo so ninu ìpàdé ifilole ayeye amin idanimo ti won nse fun iranti awon omoogun  fun odun 2024 ti won pe ni (Armed forces remembrance day ) ti won se ni ile asofin ipinle to wa lolu ilu ile wa Abuja.

Aare filan pe o je ifi emi imore han ati mimo riri ise ti awon akoni lokunrin ati lobirin naa ti won ti se lati sin ijoba ati orile-ede won pelu ise takuntakun ti won ti se ki o to dipe won dagbare Faye.

Beni osi kun seleri pe oun yoo tunbo ma se atileyin to loorin fún awon eniyan naa nipa side atunyan sipo awon to kaaju e lati me mu kí eto abo wa lori won, bi awon naa nse n daabo bo orile-ede wọn.

Leave a Reply

Back To Top