Ajo LASTMA Ti Gbesele Awon Oko Ti Ko Din Ni Ogorun Jakejado Ipinlé Eko (Iroyin Awujo Wa) Thursday, 26th October 2023.

Ajo ti o risi oro igboko gbodo oko loju popo ni ipinle Eko iyen Lagos State Traffic Management Authority LASTMA ni Iroyin so di mimo wipe, won ti gbese le awon oko ti ko din ni ogoru Jakejado ipinle naa ,ni awon oko ti won waa gunle si awon aaye ti ko to Lori afara ati awon ibudoko eyi ti o dii lulo bibo oko lowo.

Gegebi Ògbení Sola Giwa ti o je onimoran pataki fun gomina ipinle Eko lori oro igboke gbodo oko eyi ti o lewaju eso adamolekun naa, o salaye wipe, won gbé igbese yii lati le je ki Lilo bibo oko jagere ni awon Ori afara gbogbo ni ipinle Eko ati wipe lati dekun gbigbe oko si aaye ti ko to, eyi ti o Lodi si ofin Irina oko ni ipinle Eko gegebi atunte re ti odun 2018.

O menuba wipe awon agbegbe ti won ti gbese le awon oko naa ni Ejalonibu,Obalende, Apogbon, Ebute-Ero, Idumota ni erekusu Eko.

Leave a Reply

Back To Top