Alága Àjọ EFCC tí Pàṣẹ Pé Kí Àwọn Òṣìṣẹ́ Àjọ Náà Ṣe Alakale Dúkìá Wọn: Ìròyìn Itanilólobó, 26th October 2023

Alaga titun fun ajo tó n gbogun ti iwa ibaje ati ajebanu lorilede yii (Economic and Financial Crime Commission EFCC) ogbeni ola Olukoyede Lana Ojo isegun lo ti pase wipe ki awon osise ijoba ninu ajo oun bere sini se alakale ati ijewo awon Dukia ti won ti ni pelu ibamu Ilana ajo naa ati wipe wom yoo ma digba se eleyi lati le ma Fi oju oun gbogbo ti won ni hande lohun a lati ri daju pe won ko lebo leru loma kam tabu omii.

O soro ase yi jade ni olu ile ajo oun to wa ni olu ile wa Abuja Lana ode yii, gegebi Oro ti agbenuso fun ajo EFCC ogbeni Dele Oyewale so fun awon oniroyin, o ni awon osise ajo Yi yoo fi owosowopo pelu ogbeni Olukoyede lati ri daju pe won gbogun ti iwa Ajebanu lawin origun ise kookan papa julo awon to je ti ijoba lorilede Naijiria

Leave a Reply

Back To Top