Tinubu Ní Òun Ní Ìgbẹ́kẹ̀lé Nínú Gbajabiamila
Aare Bola Ahmed Tinubu ti fi da awon eniyan loju lori awuyewuye kan to n lo lowo lori eni to je olori awon osise ninu isejoba re yii, Femi Gbajabiamila, Aare soo di mimo wipe oun ni ifokantan ati igbekele kikun ninu re bee ni oun gbagbo pe ko le tase agere . Aare salaye […]
Wọ́n Ti Ṣíṣọ Lójú Ọkọ̀ Tí Yóò Máa Lọ Afẹ́fẹ́ CNG Nipinlẹ̀ Ogun
Gomina Ipinle Ogun, Omooba Dapo Abiodun ni iroyin fi lede pe o ti siso loju awon oko boosi ti yoo maa lo afefe Compressed Natural Gas ( CNG ) dipo epo bentiroluu lati le maa fi se igbokegbodo awon eniyan ipinle ohun lona ti yoo fi ro won lorun gege bi okan lara awon alakale […]
Wọ́n Rí Àwọn Òkú Ènìyàn L’oja Màálù Nipinlẹ̀ Abia
Gomina ipinle Abia, Alex Otti ti soo di mimo bayii pe Oja maluu ti won n pe ni Lokpanta Cattle Market, eyi to wa ni agbegbe Umunneochi, lopopona marose, Enugu si Portharcourt yoo di oja ti awon eniyan jakejado orileede yii yoo maa fi ojoojumo na bayii ati wipe ko ni je oja maluu nìkan […]
Àwọn Jàndùkú L’ọlọ́pa ń lò fi Ṣiṣẹ́ Nipinlẹ̀ Èkó
Awon awako lagbegbe Berger ati Oshodi nipinle Eko ni won ti n ke gbajare bayi, ti won si n soo di mimo wipe awon janduku ni awon agbofinro nlo lawon agbegbe yii lati maa gba owo lowo awon lojoojumo. Gege bi Tolulope se fi to awon oniroyin leti, o ni owo ti awon n san […]
Àwọn Mọ̀lẹ́bí Ajayi ń béèrè fún Ìdájọ́ Òdodo
Awon molebi Baba agba, eni aadorin odun 70 years, Aminu Ajayi ti o je òṣìṣẹ́ ijoba teleri ti awon jandulu kan seku pa nipinle Ogun ni won ti n beere bayi fun idajo ododo lori iku ti o pa baba ati egbon won. Iroyin soo di mimo wipe awon janduku kan lo sekolu si baba […]
Olopa ń bère fún #100, 000 owó Police Report
Okunrin kan, Oyibe Michael lo ti n ke gbajare bayi latara bi awon olopa se n beere owo ti o to egberun lona ogorun naira, #100,000 lowo re gege bi owo ti o ni lati san ki o tó lè gba ìwé pé ó fi oro tó olopa leti eyi taa mo si police report. […]
CBN Ní Òun Kò Ní Erongbà Àtẹ̀jáde Irúfẹ́ Owó Míràn Báyìí
§Ile ifowopamo apapo Ile yii, Central Bank of Nigeria (CBN) ti soo di mimo bayi pe oun ko gbero lati se afikun fun awon irufe Ipele owo ti a n na lorileede yii lodun 2024 gege bi iroyin kan se n gbee kiri. Ninu atejade kan ti eni ti o je adari leka ikansiraeni fun […]
Àwọn Ọ̀yọ́mèsì Fẹ̀hónú Hàn Lórí Àpèrè Aláàfin
Opolopo awon omo bibi ilu Ọ̀yọ́ lọ́jọ́ Iṣẹ́gun tó kọjá ni won ti n fehonu han ni woorowo leyi to mu ki won lo duro si enu ona abawole Ile ejo giga ti Ọ̀yọ́ to wa nilu Awe latari bi ijoba ipinle Ọ̀yo ati awon Ọ̀yomesi ṣe n fi oro yiyan Alaafin tuntun fale. Ninu […]
Gómìnà Sanwo-Olu Towo Boọ Ìwé Àdéhùn Tuntun
Gomina ipinle Eko, Babajide Sanwo-Olu niroyin fi lede pe o ti towo bo iwe adehun pelu awon banki meji taa mo si African Export and import Bank pelu Access Bank lati maa ṣe akoyawo awon ise akanse fun idagbasoke ipinle Eko. Iwe adehun yii ni won buwolu nibi ipade apero awon onisowo agbaye fun ti […]
Tinubu tí dá sí Rògbòdìyàn Ìpínlẹ̀ Rivers
Aare Bola Ahmed Tinubu niroyin soo di mimo bayi pe o ti da si rogbodiyon to n lo lowo bayi nipinle Rivers laarin Gomina Siminelayi fubara ati Nyesom Wike to sese kuro lori aga gomina nibe, to ti wa di minista fun olu ilu Ile wa Abuja bayi. Iroyin fi to wa leti pe ibasepo […]