Tinubu Buwọ́lu owó tí ó tó Bilionu Méjìdínlógún fún Awọn Molebi Àwọn Akoni Tó Ti D’Olóògbé
Aare Bola Ahmed Tinubu ti buwolu owo ti o to billionu mejindinlogun naira (#18bn) fun awon ebi awon akoni to subu loju ìjà l’Ojoru tó Kọjá yìí gege bí anfani fún àwọn molebi àwọn ènìyàn náà . Aare so wipe oun bù owo lu owo fun awon olóògbé náà ni ibamu pelu ise won ki […]
Sanwo-Olu ni òun yóò ọ̀rọ̀ ètò ilera lókùńkúndùn
ijoba ipinle Eko labe isakoso Gomina Babajide Sanwo-Olu ti so di mimo pe oun yoo mu oro eto ilera lokun kúndùn bayi fun awon olugbe nipinle Eko. Gomma Sanwolu so oro yi nigba to ngbalejo minista to ń risi eto ilera ati itoju nipinle naa, Dokita Tunji Alausa l’Ojoru tó kọjá yìí ni agbegbe Marina […]
Wọ́n ti ni kí àwọn Dókítà máa lò tó ọdún márùn-ún kí wọ́n tó lè rìnrìn àjò lọ sí òkè òkun
Eni to je giwa ati oga agba yan-an-yan fun Ile eko giga fasiti ti oro ìlera, University of Medical Sciences (UNIMED)eka ti Ipinle Ondo, Ojogbon Adesegun Fatusi lo ti gba ijoba orileede Naijiria nimoran bayii lori oro awon akeko jade lori oro eto ilera lawon Ile eko giga fasiti ti ijoba apapo lorileede yii, o […]
Wọ́n tí gba Atiku àti Obi nímọ̀ràn láti má ṣe fi orile-ede yii sílè l
Agbarijo awon igbimo to n pepe fun isakoso ati ayipada rede lorileede yii ti ro ẹni to ti figba kan ri je Igbakeji aare Lorileede yii, to tun je adije Dupo aare labe egbe oselu Peoples Democratic Party PDP, Alhaji Atiku Abubakar ati akegbe re latinu egbe oselu Labour, Peter Obi lati mase fi orileede […]
Ilé Ẹjọ́ Tí Wọ́gilé Ìyànsípò Ghandi Gẹ́gẹ́ bíi Ṣọ̀ún Tí Ògbómọ̀ṣọ́
Ile ejo giga to fikale silu Ogbomoso nipinle Oyo ti wogile iyansipo Oba Ghandi Olaoye gege bi Soun tuntun fun ilu Ogbomoso. E o ranti pe lojo kejo osu kesan odun 2023 taa wa yii ni ijoba ipinle Oyo kede Oluso agutan Ghandi bi Soun tuntun, ṣùgbọ́n kí ó to di Igba naa ni Kabir […]
‘A kò gbọ́dọ̀ f’ọwọ́ yẹpẹrẹ mú idibò tó ń bọ̀ yìí. – INEC (Ìròyìn Àkóyawọ́) Friday 27th October, 2023.
Ajo olominira eto idibo nile yii, Independent National Electoral Commission (INEC) ti soo di mimo wipe eto idibo sipo gomina.eyi to n bo lona yii lojo Kokanla, osu kokanla odun yii lawon ipinle kogi, Bayelsa ati Imo,o ni eto idibo naa je eyi to se Koko ti a ko gbodo fowo yepere mu labe bo […]
Ìlé Ìfowópamọ́ Àgbáyé Ṣèkìlọ̀ Lórí Ogun Tó ń lọ Lọ́wọ́ Láàárín Ísírẹ́lì àti Hamas (Ìròyìn Ìtakìjí) Thursday 26th October, 2023
ile ifowopamo agbaye ti soo di mímo bayi pe Ogun to n lo lowo lorileede isreal ati Hamas le se akoba nla-nla fun oro aje agbaye. Gege bi eni to je aare ile ifowopamo yii Ajay Banga se so lojo Ìsegun ose yii nibi ìpàdé apero kan to waye lorileede Saudi Arabia. O ni ohun […]
Ìgbìmọ̀ Alẹ́nulọ́rọ̀ ti Buwọ́lu Ẹ̀yáwó fún Iṣẹ́ Àkànṣe (Ìròyìn Ìtakìjí) Thursday 26th October, 2023
Ìgbimo àwọn alenuloro ninu isejoba apapo lorileede yii lọ́jọ́ Aje ose yìí ti buwolu ìgbésẹ̀ eyawo ti ko ni ele Lori ti o fere to bilionu meta aabo dollar $3.4 lati banki apapo agbaye (World Bank) eyi ti won fe na Lori awon eto onikoko marun otooto. Gege bi minista fun eto isuna ati isakoso […]
Ẹgbẹ́ Àwọn Oníṣòwò Gáàsì Tí D’ẹ̀bi Ọ̀wọ́ngógó rẹ̀ ru àwọn alágbàtà (Ìròyìn Àkóyawọ́) Thursday 26th October, 2023
Egbe orusowo afefe idana nile yii Nigeria Association of Liquefied Petroleum Gas Marketers ti debi owongogo to de ba eroja ohun ru awon alagbata gege awon ti o moomo n fi owo le ori eroja yii ti o mu ki o won gogo. Ẹni ti o je aare egbe yii alagba Oladapo Olatubosun lo so […]
Àwọn Àgbẹ̀ Ti Ṣe Àlàkalẹ̀ Ìṣòro Wọ́n: (Ìròyìn Àkóyawọ́) Thursday 26th October, 2023
Awon agbe lorilede yii Lana ojo Isegun ni won ti soro Lori awon isoro ti won unkoju Lori ayipada to deba oju ojo, eyin to un mu adinku ba abajade ere oko wo, ti o sin se akoba fun ere ati igbe aye won lapapo. Eyin wa Ara Abajade ipade ti egbe awon agbe yi […]