Aare Bola Tinubu Ni Iroyin Ti So Wipe Yio Wa Ni Ibi Ipade Adura Kan(Iroyin Itanilolobo) Thursday,30 November 2023
Aare Bola Ahmed Tinubu ni Iroyin so di mimo wipe yio wa ni ibi ipade adura pataki,eyi ti won yio te pepe re ni ola ti o je ojo eti ojo kinni osu kejila odunti a awa yii mini gbongan ile ijosin gbogboogbo fun awon elesin kristeini. Eyi ti a mo si National Ecumenical Center […]
Ile Ejo Gigajulo Ile Naijiria Ti Ni Ki Awon Omo Orile-ede Naijiria Maa Naa Awon Owo Ti Tele Lo(Iroyin Itanilolobo) Thursday,30 November,2023
Ile Ejo gigajulo ni ile yii ni ana ojoru ti Palase wipe,awon omo orile-ede Naijiria ni anfani lati maa naa awon Owo naira ile wa leyi ti won gbé titun re jade ni odun 2022, nibi ti a ti ri igba naira 200, Eedegbata naira 500, ati egberun kan naira 1000. Ile Ejo ti pase […]
Ijoba Ibile Idagbasoke Agbado Okeodo Pa Owo Wole Lati Ara Ero Ibanisoro (Iroyin Awujowa) Monday, 27 November,2023
Ijoba ibile idagbasoke Agbado okeodo ni ipinle Eko Ti pinu lati maa pa won wole larata ero ibanisoro lodo awon oloko-owo fun odun 2024. Erongba yii di mimo lati enu alagba ijoba ibile idagbasoke oun,Hon. David Oladapo Famuyiwa, ninu iforowanilenuwo ti o waye ni ibi apero eto isuna odun 2024 ni ojobo ose ti o […]
Awon Oloko Ti Fi Aidunu Won Lori Ipo Ti Awon Opopona Kan Wa Ni Ipinlé Eko(Iroyin Awujowa) Monday, 27 November 2023
Awon oloko ni awon agbegbe kan labe ijoba ibile Alimosho ni ipinle Eko ni won ti fi aidunu won han si ijoba ipinle oun lojo ano latari bi ogbara to gboju ona latara ojo ti o ro lojo aiku oun se ba ise je mowon lowo ti osi so opolopo oko di kudeti soju popo. […]
Awon Afurasi Agbebon Kan Ni Won Se Ikolu Si Awon Agbegbe Kan Ni Ipara Remo Ati Ode Remo(Iroyin Awujowa) Monday,27 November 2023
Awon afurasi agbebon kan ni Iroyin fi lede wipe won se ikolu si awon agbegbe kan ni Ipara Remo ati Ode Remo ti awon omo ile eko giga gbogbonise ti gateway Sapade mulesi labe ijoba ibile Ariwa Remo ni Ipinle Ogun ti won si yibon ba awon akeeko lokurin kan tun ba awon akeeko lobinrin […]
Komisona Olopa Ni Ipinlé Enugu Ti Pase Ki Won Beere Isé Iwadi Ni Pereu (Iroyin Akoyawo) Monday, 27 November 2023
Komisona olopa ni ipinlé Enugu, Ògbení Kanayo Uzuegbu ni o ti n pase wipe ki iwadi o bere ni pereu lori awon Iwa kudie kudie kan ti o n waye laarin awon agbofinro ni agbegbe Nsukka ni ipinlé naa. O ni, oun ti pase fun igbakeji komisona ipinle yii lati tete bere iwadi lati le […]
Aare Bola Tinubu Ti Fi Lede Wipe, Ile Ifopo Ti O Je Ti Ibile Yio Beere Isé Laipe(Iroyin Akoyawo) Monday,27 November 2023
Aare Bola Tinubu ni o ti ta awon omo orile-ede Naijiria ni olobo wipe, awon ile ifopo ti o je ti ibile yio beer isé laipe Jojo Te o ba gbagbe wipe,leyin osu die ti Aare de Ori alefa ni o ti se ikede wipe ile ifopo ti o nbe ni ilu port-harcourt yio beer […]
Aare Bola Tinubu Ti Dasi Awo Ti O Wa Laarin Gomina Ipinle Ondo Ati Igbakeji Re (Iroyin Itanilolobo) Monday,27 November 2023
Aare Bola Ahmed Tinubu ni o ti daasi awon ti nlo ni ipinle Ondo laarin gomina Rotimi Akeredolu ati igbakeji re Ògbení Lucky Ayedatiwa. Eniti o je onimoran pataki fun Aare Tinubu lori oro ifilede , Ajuri Ngelalelo fi oro oun lede lana ojo aiku, o salaye wipe ,gomina Akeredolu ati igbakeji re Ayedatiwa ti […]
Isejoba Aare Tinubu Ti Setan Lati Se Eto Bi Awon Ile Eko Giga Fasiti Yio Se Wa Ni Ominira (Iroyin Itanilolobo) Monday,27 November 2023
Ninu Ero mimu idagbasoke ba ilu ati yiyo ajaga kuro lorun ijoba apapo, Are Bola Tinubu ti so di mimo wipe isejoba oun yoo maa bojuwo eto siso awon ile eko giga fasiti kakakiri orilede yi di ominira eyi ti yoo maa mu won se oun gbogbo lowo ara won lai duro de ijoba. Eniti […]
Ajo SERAP Ti Ni Ki Banki Agbaye Dawo Owo Yiya Duro Fun Awon Ipinle Merindinlogoji (Iroyin Itanilolobo) Monday,27 November 2023
Ajo kan ton mojuto eto isuna ati ise isiro Iyen Socio-Economic right and accountability project SERAP lano ojo aiku ni won ti ro are banki agbaye ogbeni Ajay Banga lati dawo yiya awon ipinle merindinlogoji orilede Naijiria yi lowo duro latari bi won ti nse owo ilu kumokumo papajulo awon owo ti won ti ya […]