Gomina Ipinle Osun Ti Palase Fun Awon Agbofinro Lati Beere Isé Iwadi(Iroyin Akoyawo) Friday,24 November,2023
Gomina ipinle Osun, Ademola Adeleke ti pase wipe ki awon agbofinro beere isé iwadi won lori awon iwolule kan ti o waye ni ale ana ni oja Oshogbo,ti o je olu ilu ipinle naa. Iwadi fi idi re mule wipe awon eniyan kan ni won kolu awon oja meta kan, ti won si woo awon […]
Oga Agba Ile Isé Olopa Ti So Di Mimo Wipe Ile Isé Olopa Nilo Ooko Merin-Merin Kaakiri Ilu (Iroyin Itanilolobo) Friday,24 November,2023
Oga Agba ile isé Olopa, inspector Gen.Kayode Egbetokun, so di mimo wipe, eka ile isé Olopa kankan, nilo ooko isé merin-merin otooto kakiri ilu. O so oro yii di mimo ni ojo isegun ose yii ni ile igbimo asofin wipe,Owo teere esun teere ti won n fun awon yii, je ipenija nla ti Ile isé […]
Minisita Teleri Fun Oro Isé Ati Ile Gbigbe Lorile-ede Yii Ti Gba Ijoba Apapo Ati Awon Alenuloro Ni Imoran Lori Oro Ile Gbigbe Ni Ile Yii (Iroyin Itanilolobo) Friday,24 November,2023
Minisita teleri leka oro ise ati ile gbigbe, Babatunde Raji Fashola lo so opolopo oro fun ijoba apapo ati awon alenuloro idi ti won fi gbudo se atileyin fun eto ile gbigbe awon ara ilu, paapa julo lati gbedigina isoro ti o ba awon ti o ni ile Lori jaa. Fashola so oro yii di […]
Ajo National Economic Council Ti So Wipe Ijoba Apapo Ti N Gbé Igbese Lati Se Atileyin Eto Ogbin Fun Gbogbo Ipinle Lorile-ede Naijiria (Iroyin Itanilolobo) Friday,24 November,2023
Ajo ti o n se amojuto idagbasoke ilu, iyen National Economic Council lo so di mimo ni ana wipe, ijoba apapo n se Igbese lati se atileyin eto ogbin fun gbogbo ipinle merin-din-logoji ni orile-ede Naijiria,ijoba n gbero lati se idasile isé ti yio to milionu mejidinlogun ,titi kan awon agbe ti yoto egbeerun-lona-ogorun kakiri […]
Ile Isé Omo Ogun Oju Omi Lorile-ede Naijiria Ti Reburu Oko Oju-Omi Nla Kan(Iroyin Itanilolobo) Friday, 03 November 2023
Ile isé Omo ogun oju omi Lorile-ede Naijiria, Nigeria Navy ni won ti so di mimo wipe, won reburu oko oju omi nla kan, eyiti won fin gbé epo ni ona aito lati orile-ede yii, ni ibudo epo tii Atlas Cove,eyiti o je eka kan lara ile isé ti o risi oro epo bentiro ni […]
Adajo Agba Kan Ni Ilu Abuja Ti So Fun Ajo EFCC Ki O Jowo Godwin Emefiele (Iroyin Itanilolobo) Friday,03 November,2023
Lana ojobo ti o je ojo keji osu kokanla odun ti a wa yii, ni Adajo O.Adeniyi ti Ile ejo giga ti o fidi kale si ilu Abuja , pa ni ase wipe, ki ajo ti o gbogun ti Iwa ajebanu ati sise owo ilu kumo-kumo , Economic and Financial Crime Commission EFCC ki o […]
Egbe Awon Osise Ati Trade Union Congress Ni Won Ti Bu Enu Àte Lu Iwa Ti Gomina Hope Uzodinma Hu (Iroyin Itanilolobo) Friday,3rd November 2023
Egbe awon osise ni orile-ede yii,iyen Nigeria Labour Congress NLC, ati akegbe re ,Trade Union Congress TUC ni won jo bu enu àte lu Iwa ti Gomina ipinle Imo, Hope Uzodinma hu latari ikolu ti awon kan se si Aare egbe awon osise, Ògbení Joe Ajaero ni ipinlé Imo ni ojoru ose yii, ni asiko […]
Igbimo Isakoso Awujo Kan Ni Ipinle Oyo Ti Rawo Ebe Si Eka Isé Ijoba Apapo (Iroyin Awujowa) Monday,30th October 2023
Igbimo isakoso awujo kan ni ipinlé Oyo ni won to rawo ebe si eka ile isé ijoba apapo ti o mojuto oro ise ati awon agbasese ti won mojuto isé oju ona marose Ibadan si Oyo, Ogbomosho ati Ilorin lati falemo isé opopona oun latari ijamba ti o n waye nibe ni ojo kerinla osu […]
Ajo Olopa Ipinlé Ogun Ti Rowoto Awon Omo Wewe Meji Kan (Iroyin Awujowa) Monday,30th October 2023
Ajo olopa ni ipinlé Ogun ni o ti rowoto awon omo wewe meji kan ti ojo ori won koju mefa ati mesan lo lori esun wipe won danasun ile eko won eyi ti o wa ni agbegbe Isheri -Olofin ni abe ijoba ibile Ifo ni ipinle Ogun. Oga olopa Omolola Odutola ti o je alukoro […]
Ijoba Ipinle Eko Ti Daa Awon Ile Itaja Woo Ni Agbegbe Ikotun (Iroyin Awujowa) Monday,30th October 2023)
Awon olokowo ati oloja ti ijoba daa ile itaja won woo latari imugboro agbegbe ikotun ni abe ijoba ibile Alimosho ni ipinlé Eko ni won ti ké gbajari sita fun iranwo. Iroyin je ko di mimo wipe, awon ile itaja ti o to aadorun ni ijoba daawo ni odun 2020, ti awon osise ijoba ipinle […]