Isele Ijamba Oko Oju-rin Waye Ni Ilu India Lana Ojo Aiku (Iroyin Akoyawo) Monday,30th October 2023
O kere pin eniyan bi metals ni o ti gbé emi mi ,ti awon miran ti o to aadota si ti fi arapa yanayana nibi ti oko oju-rin meji kan ti kolu ara won ni apa guusu ila oorun orile-ede India. Isele oun ti won ni o waye no ojo aiku ana ni eka […]
Minisita Fun Oro Eko Ni Orile-ede Yii Ni O Ti Fi Erongba Ijoba Apapo Han Lori Eto Eko Ni Ile Yii(Iroyin Akoyawo) Monday,30th October 2023
Eniti o je Minisita fun oro eko ni orile-ede yii, Tahir Mamman ni o ti fi erongba ijoba apapo han lori a ti gbogun ti awon idojuko ti o n yo awon ogowere lenu eko eleyi ti o n ranle gbengben ni orile-ede yii lowo-lowo. O fi oro oun lede fun awon oniroyin ni ojo […]
Egbe Oselu APC Ti Ko Iwe Si Egbe T’on Baniwi Ninu Ajo Amofin Orile-ede Yii Lori Iwa Ifenu-tenbele Ejo Ile Ejo Gigajulo Ile Yii (Iroyin Akoyawo) Monday,30th October 2023
Egbe oselu ti o n se ijoba lowo-lowo ni orile-ede Naijiria iyen All Progressive Congress ni o ti ko iwe si egbe ti o n baniwi ninu ajo amofin orile-ede yii lori Iwa ifenu tenbele ejo ile ejo giga julo ni orile-ede yii ti alaga apapo egbe Oselu Labour Julius Abure ati agbenuso fun ipolongo […]
Omodekunrin Eni Odun Merinla Gba Emi Ara Re Ni Ipinlé Cross -River (Iroyin Itanilolobo) Monday,30th October 2023
Ninu ilailo ati iyalenu ni awon olugbe Ekondo ni ilu Calabar ipinle Cross -River was, latari bi Omodekunrin kan eni odun merinla se fi okun bata gba emi ara re. Omodekunrin oun ti oruko re nje Donald ni won ni ongbe pelu iya-iya re ni apa guusu ilu oun. Iroyin Fi lede wipe,okan lara ore […]
Awon Janduku Oloselu Kan Ni Won Ti Ina Bo Ile Igbimo Asofin Ni Ipinlé River (Iroyin Itanilolobo) Monday,30th October 2023
Ile igbimo asofin ti ipinle Rivers ni iroyin fi lede wipe awon janduku oloselu kan ni ipinle oun ti Ina bo latari Igbese ile igbimo oun lati ro adari re, Hon. Edison Ehie ati gomina Ipinle naa, Sir Siminalayi Fubara loye ni oni ojo aje. Okan lara awon oga olopa ni ipinlé naa, ti ko […]
Senato Kabiru Marafa Ti Ni Aare Tinubu Setan Lati Ba Awon Adije Dupo Ti Won Fidiremi Sise Po (Iroyin Itanilolobo) Monday,30th October 2023
Okàn lara awon senato teleri ni orile-ede Naijiria ti o soju arin gbun-gbun ipinle Zamfara ,Kabiru Marafa ni o ti fi lede ni opin ose ti o koja yii wipe, Aare Bola Tinubu ti setan lati fi owosowopo pelu awon alatako re ti won dije du ipo Aare ,ti won si fi idi remi lati […]
Awon Afobaje Ni Ipinlé Oyo Ti Ro Ile Ejo Lati Da Gomina Seyi Makinde Lowoko (Iroyin Akoyawo) Friday, 27th October,2023.
Awon Afobaje ni Ilu Oyo ti won n pe ni oyo-mesi, ni won n ro ile ejo wipe ki o ba awon da Gomina ipinle Oyo Seyi Makinde lowoko, lati mayoo awon kuro bi Eniyo jiga, ninu awon tiwon fe se afihan Eniti yo je Alaafin oyo. Awon afobaje ti won n pe ipejo oun […]
Gomina Ipinle Ondo Ti Ko Eti Ogboi Si Ebe Ti Igbakeji Re Nbe (Iroyin Akoyawo) Friday,27th October,2023
Gomina ipinle Ondo,Ògbení Rotimi Akeredolu ni o ti ko eti ogboi bayi si awon ebe ti igbakeji re ogbeni Lucky Ayedatiwa nbe lori awon rogbodiyan kan ti o n lo lowo ni eka Oselu ni ipinlé naa. Ogbeni Akeredolu ni o so ninu oro re lati enu eniti o je onimoran pataki fun lori oro […]
Ile Ejo Gigajulo Ile Naijiria Ti Fi Opin Si Awuyewuye Ti O Jeyo Leyin Idibo Aare Lorile-ede Yii (Iroyin Akoyawo) Friday,27th October 2023
Lana ojobo ti o je ojo kerindinlogbon osu kewa odun ti a wa yii ni ile ejo gigajulo ni ile yii fi opin si ija awuyewuye ati idukoko moni lori oro ijawe olubori ti awon elegbe Oselu lorisirisi ni ibi ti a ti ri egbe Oselu People’s Democratic party leyi ti Alhaji Atiku Abubakar ti […]
Alaga Egbe Oselu APC Ti Gba Awon Adije Dupo Aare Lati Inu Egbe Oselu PDP Ati Labour N’imoran Lori Oro Aare Tinubu (Iroyin Itanilolobo) Friday,27th October,2023
Alaga Apapo fun egbe oselu All progressive congress APC, Abdullahi Ganduje, Lana ojobo ni o n so fun adije dupo Aare Lati inu egbe oselu peoples Democratic Party, Alhaji Atiku Abubakar ati adije dupo ni abe egbe oselu Labour Peter Obi, wipe aaye sii wa fun won lati tun dije dupo Aare miran leyin Saa […]