Ajo LASTMA Ti Gbesele Awon Oko Ti Ko Din Ni Ogorun Jakejado Ipinlé Eko (Iroyin Awujo Wa) Thursday, 26th October 2023.
Ajo ti o risi oro igboko gbodo oko loju popo ni ipinle Eko iyen Lagos State Traffic Management Authority LASTMA ni Iroyin so di mimo wipe, won ti gbese le awon oko ti ko din ni ogoru Jakejado ipinle naa ,ni awon oko ti won waa gunle si awon aaye ti ko to Lori afara […]
Ile Ejo Giga Ti O Kale Si Ilu Ogbomosho Ti Wogile Iyansipo Oba Ghandi Olaoye (Iroyin Awujo wa) Thursday,26th October,2023
Ile ejo giga to Fi ikale si ilu Ogbomosho ni ipinle Oyo lana ojoru ti wogile iyansipo oba Ghandi Olaoye gegebi soun ti ilu ogbomosho. Ijoba ipinle Oyo ni won ti kede olusoaguntan Ghandi Olaoye gegebi soun ti ilu ogbomosho ni ojo kejo osu kesan odun ti a wa yii lasiko ti Omo oba […]
Awon Olugbe Ni Agbegbe Abakaliki Ni Ipinle Ebonyi Ti Ké Gbajere Sita
Awon olugbe ni agbegbe Abakaliki ni ipinle Ebonyi, ti n ké gbajare bayi latari bi awon alokolounkigbe n se Fi ojojumo yo won lenu ni agbegbe oun. Iroyin fi ye wa wipe, ojojumo ni awon jaguda Pali oun ati awon omo elegbe okunkun n fi damu awon olugbe ti o wa ni ijoba ibile […]