Awon agbe lorilede yii Lana ojo Isegun ni won ti soro Lori awon isoro ti won unkoju Lori ayipada to deba oju ojo, eyin to un mu adinku ba abajade ere oko wo, ti o sin se akoba fun ere ati igbe aye won lapapo.
Eyin wa Ara Abajade ipade ti egbe awon agbe yi se lori akoba ti ayipada oju ojo se ninu ise won, ipade naa lo waye ni eka ajo ton risi oro ayika ati idagbasoke re to wa nilu ogbomosho ni ipinle Oyo, gegebi ogbeni Paul Ojo owo to ba awon oniroyin soro seso, o ni opolopo awon agbe ni koni oye to lori oro ayipada oju ojo oun sugbon ti won saadede sakiyesi pe ere oko awon o se daradara to, eyin naa lo fa, ti opolopo fi ni irewesi okan lojuna ati dara de ise oun bi tatehin wa ati wipe wahala ti awon Fulani daran daran un fun awon agbe ni awon agbe gbe Iwo-orun Guusu orileede yi je okan lara isoro ti awon agbe dojuko.
Eni to je akowe agba fun egbe yii ogbeni sulaimon Arigba bu wa to awon egbe ti won je omo egbe naa lati ri daju pe won na loju opo ikansiraeni leyi ti yoo ma ta won lolobo lorekore Lori awon igbese kilokan ati ayipada to nise pelu Oro ise won.