Ile igbimo asofin ti ipinle Rivers ni iroyin fi lede wipe awon janduku oloselu kan ni ipinle oun ti Ina bo latari Igbese ile igbimo oun lati ro adari re, Hon. Edison Ehie ati gomina Ipinle naa, Sir Siminalayi Fubara loye ni oni ojo aje.
Okan lara awon oga olopa ni ipinlé naa, ti ko Fi oruko ara re lede Jeri si isele naa wipe, o na ajo olopa ati ajo pana-pana ni ilagun ti o po ati idamu lati paa Ina oun sugbon lowo-lowo yii, oko eso alaabo bi metadinlogun pelu ihamora ni o ti wa ni ibi isele naa pelu awon eso alaabo ti o je ti ijoba apapo ti o n lo bi aadoota ni won ti gunle si ibi isele naa lati se iwadi ohún ti o bi isele oun.