Awon Oloko Ti Fi Aidunu Won Lori Ipo Ti Awon Opopona Kan Wa Ni Ipinlé Eko(Iroyin Awujowa) Monday, 27 November 2023

Awon oloko ni awon agbegbe kan labe ijoba ibile Alimosho ni ipinle Eko ni won ti fi aidunu won han si ijoba ipinle oun lojo ano latari bi ogbara to gboju ona latara ojo ti o ro lojo aiku oun se ba ise je mowon lowo ti osi so opolopo oko di kudeti soju popo. Awon agbegbe toro oun kan ni Egbeda, Idimu, Isheri-Oshun, Akowonjo.

Oko lara awon oloko toro naa ka lara ni irin ajo ile oun si ile ijosin koju iseju melo kan lo sugbon lakoko ti ojo bati ro bayi oun maa n fere sun soju ona latara sunkere fakere oko loju popo

Nigbati awon akoroyin kan si eniti o je komisona fun oro ifilede ni ipinle naa Gbenga Omotoso, o salaye wipe awon nsise takun takun labenu lori oro agbegbe naa ti ise naa yoo si maa foju han si gbangba laipe.

 

Leave a Reply

Back To Top