Gómìnà Sanwo-Olu Towo Boọ Ìwé Àdéhùn Tuntun
Gomina ipinle Eko, Babajide Sanwo-Olu niroyin fi lede pe o ti towo bo iwe adehun pelu awon banki meji taa mo si African Export and import Bank pelu Access Bank lati maa ṣe akoyawo awon ise akanse fun idagbasoke ipinle Eko. Iwe adehun yii ni won buwolu nibi ipade apero awon onisowo agbaye fun ti […]
Tinubu tí dá sí Rògbòdìyàn Ìpínlẹ̀ Rivers
Aare Bola Ahmed Tinubu niroyin soo di mimo bayi pe o ti da si rogbodiyon to n lo lowo bayi nipinle Rivers laarin Gomina Siminelayi fubara ati Nyesom Wike to sese kuro lori aga gomina nibe, to ti wa di minista fun olu ilu Ile wa Abuja bayi. Iroyin fi to wa leti pe ibasepo […]
Ààrẹ Bọ́lá Tinúbú Àti Gómìnà Ẹgbẹ́ Ọ̀ṣèlú PDP Ti Dáwọ́ Ìyọnípò Fubara Dúró, Agbófinró Mún Àwọn Olùfẹ̀hónún Hàn
Ààrẹ Bọ́lá Tinúbú Àti àwọn gómìnà ẹgbẹ́ òṣèlú PDP lọ́jọ́ ìṣẹ́gun Tuesday ti gbé ìgbé sẹ̀ láti Dáwọ́ Ìyọnípò gómìnà Ìpínlẹ̀ Rivers siminalayi Fubara Dúró, Ààrẹ ṣe ìpàdé pẹ̀lú Gómìnà náà àti Ọ̀gá rẹ̀, tó kúrò lórí àlééfà tó tún jẹ́ mínísítà olú ìlú wa Àbújá, Nyesom Wike, nílé ìjọba ní Àbújá, Gómìnà Ìpínlẹ̀ Bouchi, […]
Igbimo Isakoso Awujo Kan Ni Ipinle Oyo Ti Rawo Ebe Si Eka Isé Ijoba Apapo (Iroyin Awujowa) Monday,30th October 2023
Igbimo isakoso awujo kan ni ipinlé Oyo ni won to rawo ebe si eka ile isé ijoba apapo ti o mojuto oro ise ati awon agbasese ti won mojuto isé oju ona marose Ibadan si Oyo, Ogbomosho ati Ilorin lati falemo isé opopona oun latari ijamba ti o n waye nibe ni ojo kerinla osu […]
Ajo Olopa Ipinlé Ogun Ti Rowoto Awon Omo Wewe Meji Kan (Iroyin Awujowa) Monday,30th October 2023
Ajo olopa ni ipinlé Ogun ni o ti rowoto awon omo wewe meji kan ti ojo ori won koju mefa ati mesan lo lori esun wipe won danasun ile eko won eyi ti o wa ni agbegbe Isheri -Olofin ni abe ijoba ibile Ifo ni ipinle Ogun. Oga olopa Omolola Odutola ti o je alukoro […]
Ijoba Ipinle Eko Ti Daa Awon Ile Itaja Woo Ni Agbegbe Ikotun (Iroyin Awujowa) Monday,30th October 2023)
Awon olokowo ati oloja ti ijoba daa ile itaja won woo latari imugboro agbegbe ikotun ni abe ijoba ibile Alimosho ni ipinlé Eko ni won ti ké gbajari sita fun iranwo. Iroyin je ko di mimo wipe, awon ile itaja ti o to aadorun ni ijoba daawo ni odun 2020, ti awon osise ijoba ipinle […]
Isele Ijamba Oko Oju-rin Waye Ni Ilu India Lana Ojo Aiku (Iroyin Akoyawo) Monday,30th October 2023
O kere pin eniyan bi metals ni o ti gbé emi mi ,ti awon miran ti o to aadota si ti fi arapa yanayana nibi ti oko oju-rin meji kan ti kolu ara won ni apa guusu ila oorun orile-ede India. Isele oun ti won ni o waye no ojo aiku ana ni eka […]
Minisita Fun Oro Eko Ni Orile-ede Yii Ni O Ti Fi Erongba Ijoba Apapo Han Lori Eto Eko Ni Ile Yii(Iroyin Akoyawo) Monday,30th October 2023
Eniti o je Minisita fun oro eko ni orile-ede yii, Tahir Mamman ni o ti fi erongba ijoba apapo han lori a ti gbogun ti awon idojuko ti o n yo awon ogowere lenu eko eleyi ti o n ranle gbengben ni orile-ede yii lowo-lowo. O fi oro oun lede fun awon oniroyin ni ojo […]
Egbe Oselu APC Ti Ko Iwe Si Egbe T’on Baniwi Ninu Ajo Amofin Orile-ede Yii Lori Iwa Ifenu-tenbele Ejo Ile Ejo Gigajulo Ile Yii (Iroyin Akoyawo) Monday,30th October 2023
Egbe oselu ti o n se ijoba lowo-lowo ni orile-ede Naijiria iyen All Progressive Congress ni o ti ko iwe si egbe ti o n baniwi ninu ajo amofin orile-ede yii lori Iwa ifenu tenbele ejo ile ejo giga julo ni orile-ede yii ti alaga apapo egbe Oselu Labour Julius Abure ati agbenuso fun ipolongo […]
Omodekunrin Eni Odun Merinla Gba Emi Ara Re Ni Ipinlé Cross -River (Iroyin Itanilolobo) Monday,30th October 2023
Ninu ilailo ati iyalenu ni awon olugbe Ekondo ni ilu Calabar ipinle Cross -River was, latari bi Omodekunrin kan eni odun merinla se fi okun bata gba emi ara re. Omodekunrin oun ti oruko re nje Donald ni won ni ongbe pelu iya-iya re ni apa guusu ilu oun. Iroyin Fi lede wipe,okan lara ore […]