Ẹgbẹ́ Àwọn Oníṣòwò Gáàsì Tí D’ẹ̀bi Ọ̀wọ́ngógó rẹ̀ ru àwọn alágbàtà (Ìròyìn Àkóyawọ́) Thursday 26th October, 2023

Egbe orusowo afefe idana nile yii Nigeria Association of Liquefied Petroleum Gas Marketers ti debi owongogo to de ba eroja ohun ru awon alagbata gege awon ti o moomo n fi owo le ori eroja yii ti o mu ki o won gogo. Ẹni ti o je aare egbe yii alagba Oladapo Olatubosun lo so oro yii fin awon asofin lana ojo Aje. O ni ipese afefe idana yii ko dinku lati orisun re bee oni wahala KO tii tidi re se yo ati wipe oye ti won si n taa fan awon ile ise to n gbaa wole yii ti o je milionu mesan naira o din belenja ti won n ta metric toomu Lona Ogun zo metric tonnes o ni oye yii naa ni won so n taa, o wa je iyalenu lati ri pe won ti wa fi owo le koja bo ti ye lo tobee ti won fi n taa ni #16.8 million naira ìyẹn million metadinlogun o din die.

Leave a Reply

Back To Top