Ẹgbẹ́ Òṣìṣẹ́ ń fi Àìdunú Hàn

Agbarijo awon egbe osise lorilede yi ti fi aidunu won han latari bi ijoba apapo se un fi Oro asoyepo to wa laarin won fale lori awon etoo ti won un bere fun lati owo ijoba eyi ti yoo le mu Ara de awon ati ara ilu lapapo latari owo Irawo ori epo ti ijoba apapo yoo owo re ni kete ti Aare Bola Tinubu gba opa isejoba gegebi Aare orileede yii.

Awon egbe osise yii ti wa so di mimo wipe, iyanse lodi ti won un gbero re tele, eyi ti ijoba apapo dawo re ko latari awon asoyepo pelu adehun ti won ba won se ni won tin unreti awon imuse ati adehun naa bayii ko to di ogbon ojo osu kewa ti a wa ninu re.
Won ni bibeke awon yo gunle iyanselodi, leyi ti awon o ni bun ijoba apapo gbo ki o to di pe awon gbe igbese naa.

Gegebi eni to je agbenuso fun ajo you Benson Upab se so fun awon oniroyin Lana ojo isegun, Oni Lara awon asoyepo ti ijoba apapo ba won se, oun ni lati ma San egberun Loma marun dinlogoji Naira (35,00) gegebi owo OSU osise to kerejulo. Losun ati pipe SE awon oko ti yoo ma lo agege gaasi dipo Epo bentiro pelu awon ohun amayederun miran ti yoo le marade awon osise ati gbogbo omo Naijiria lapapo.

Leave a Reply

Back To Top