Ile Ejo Giga Ti O Kale Si Ilu Ogbomosho Ti Wogile Iyansipo Oba Ghandi Olaoye (Iroyin Awujo wa) Thursday,26th October,2023

Ile ejo giga to Fi ikale si ilu Ogbomosho ni ipinle Oyo lana ojoru ti wogile iyansipo oba Ghandi Olaoye gegebi soun ti ilu ogbomosho.

 

Ijoba ipinle Oyo ni won ti kede olusoaguntan Ghandi Olaoye gegebi soun ti ilu ogbomosho ni ojo kejo osu kesan odun ti a wa yii lasiko ti Omo oba Kabir Laoye ti o je okan lara awon omo oye ti so di mimo wipe, oro oye naa sii wa ni ile ejo ati wipe ile ejo palase wipe ki ijoba ipinle Oyo dekun a kede enikeni gegebi soun ti ilu ogbomosho titi di igba ti ejo oun yio Fi yanju sugbon ti ijoba ipinle Oyo ko eti ikun

 

  1. Eyi naa lo fa ti ile ejo giga oun Fi palase fun awon afobaje ni ilu ogbomosho lati gbé igbese lori yiyan oba titun ati wipe ona ti won gba yan oba Ghandi je eyi ti ko ba ofin mu.

Leave a Reply

Back To Top