Ìlé Ìfowópamọ́ Àgbáyé Ṣèkìlọ̀ Lórí Ogun Tó ń lọ Lọ́wọ́ Láàárín Ísírẹ́lì àti Hamas (Ìròyìn Ìtakìjí) Thursday 26th October, 2023

ile ifowopamo agbaye ti soo di mímo bayi pe Ogun to n lo lowo lorileede isreal ati Hamas le se akoba nla-nla fun oro aje agbaye. Gege bi eni to je aare ile ifowopamo yii Ajay Banga se so  lojo Ìsegun ose yii nibi ìpàdé apero kan to waye lorileede Saudi Arabia. O ni ohun to n sele yii laarin Isreal ati Gaza je ohun to lewu pupo to le mu ifaseyin ba eto oro aje opolopo lorileede lagbaye. Ninu isele Ogun yii ri iroyin ti soo do mimo bayi pe ko din ni egberun marun eniyan ti o ti doloogbe latara re bayi.

Leave a Reply

Back To Top