Isejoba Aare Tinubu Ti Setan Lati Se Eto Bi Awon Ile Eko Giga Fasiti Yio Se Wa Ni Ominira (Iroyin Itanilolobo) Monday,27 November 2023

Ninu Ero mimu idagbasoke ba ilu ati yiyo ajaga kuro lorun ijoba apapo, Are Bola Tinubu ti so di mimo wipe isejoba oun yoo maa bojuwo eto siso awon ile eko giga fasiti kakakiri orilede yi di ominira eyi ti yoo maa mu won se oun gbogbo lowo ara won lai duro de ijoba.
Eniti are gbenu re foro oun lede ti o je minisita fun idagbasoke Niger Delta Onimo ero Abubakar Momor nibi ipejopo asekagba eto eko elekejidinlaadota tile eko giga fasiti Benin, oni are ni idaniloju ti o muno doko lori igbese oun bi o je wipe gbese owo osu awon osise fasiti je oun ti ko dun mo ninu papajulo bi won ti dawo iyanselolodi duro ti ijoba naa yoo si maa San owo osu merin fun won

Tinubu tun se Ileri siwaju sii wipe awon yoo maa sise po pelu ajo TETFUND lati tunbo kun awon ile eko giga fasiti nipa nibi awon iyara ikawe ati awon oun elo miran nitori isejoba oun koni fowo yepere mu eto eko ni orile-ede Naijiria.

Leave a Reply

Back To Top