Okunrin kan, Oyibe Michael lo ti n ke gbajare bayi latara bi awon olopa se n beere owo ti o to egberun lona ogorun naira, #100,000 lowo re gege bi owo ti o ni lati san ki o tó lè gba ìwé pé ó fi oro tó olopa leti eyi taa mo si police report.
Oyibe salaye fun awon oniroyin lojo Aje tó kọjá yìí wipe oko akero kan lagbegbe Mowe njoba ibile Obafemi Owde lasiko ti oun n gbiyanju lati yipo pada si ona ti oun ti n bo lọ ṣàdédé forí gbárí pẹ̀lù ọkọ̀ òun.
O ni nigbati awon olopa de ibi isele naa, won bere iwe oko lowo oun ti oun si ko akero ti o forigbari pelu oun ninu isrle yìí, ó ní dẹ́rẹ́bà ọkọ̀ náà kò ri iwe oko ko sile bi o tile je pe won fidi re mule pe ó ti muti yo. O ni lasiko ti oun wa kan si ile ise madandofo ti oko òun wà lábẹ́ àkóso wọn lórí ọ̀rọ̀ náà, wọ́n fi yẹ òun wipe oun gbodo gba iwe olopa gbo si taa mo si POLICE REPORT ki won to le da si oro naa. O ni nigbati agbenuso fun ile iṣẹ́ olopa eka ti ipinle Ogun, SP. Omolola Odutola gbo si oro yii o je ko di mimo wipe looto ni iwe ifesun to olopa leti yii je iwe ijoba ti ara ilu ni lati sanwo fun sugbo ko egberun lona ogorun ti won pe yii.