Tinubu Ní Òun Ní Ìgbẹ́kẹ̀lé Nínú Gbajabiamila

Aare Bola Ahmed Tinubu ti fi da awon eniyan loju lori awuyewuye kan to n lo lowo lori eni to je olori awon osise ninu isejoba re yii, Femi Gbajabiamila, Aare soo di mimo wipe oun ni ifokantan ati igbekele kikun ninu re bee ni oun gbagbo pe ko le tase agere .

Aare salaye siwaju sii Lori oro naa lojo Aje ose yìí ṣáájú ki o to di akoko ti awon igbimo alenuloro ninu ijoba apapo joko ipade ti won se náà nilu Abuja.
O ni gbogbo awuyewuye to n lo lowo ati esun ti won n ka si Gbajabiamila lese lasiko yii je asise ti o seese ki o waye lati owo re ti oun si mo pe yoo se atunse lesekese.

 

Leave a Reply

Back To Top