Close sidebar

Ajo ICPC Ti Ro Awon Omo Orile-ede Naijiria Lati Faa Oju Ro Si Iwa Ajebanu (Iroyin Itanilolobo) Monday,11 December 2023

Ajo olominira ti o n gbogun ti iwa ibaje ati awon kudie kudie miran iyen independent corrupt practices and other related offenses commission (ICPC) ni o ti ro omo orilede Naijiria lati se ara won lokan fi owo sowopo gbogun ti iwa ajebanu owo ilu bi o ti je wipe o je ohun kan ti on fa eto isuna orilede yi seyin ti o si ndena ilowisaju re.

Nigbati komisona agba fun ajo oun ni ipinle Eko nsoro ni ibi iwode ati eto isiti ti won gbe kale lori igbogunti ajebanu ati sise owo ilu kumokumo’ Kabir Elelu so di mimo wipe bi mutumuwa omo orilede yi ba mu ipinu isokan lati so iwa ajebanu oun di igbagbe ni orile ede yi’ yio seese nitori eniyan lowa nidi ibaje eniyan naa ni yoo si le se atunse ti o to lori re.

O ni latari eyi awon ti gbe egbe igbogunti iwa ibaje kale ni awon ile eko alakobere ati ile ise giga jake jado orile ede lati le ko ise rere ati iwa otito Mo eko bi won ti ndagba sinu ise ilu.

Leave a Reply

Back To Top