Close sidebar

Gomina Seyi Makinde Gba Aami Eye Gegebi Gomina ti To Taayo Fun Odun 2023(Iroyin Itanilolobo) Monday,11 December 2023

Gomina lpinle Oyo, onimo – ero Seyi Makinde ni Iroyin fi lede wipe, o ti gba aami – eye gegebi Gomina ti o lamilaka fun odun 2023.

Iroyin fi ye wa wipe, loni ojo kokanla osu kejila odun ti awa yii, gomina meta ti won yan kakakiri orile – ede yii, ti won si Yan wipe o koju osuwon fun Ami eye ti odun yii eyi ti Ile – ise iwe Iroyin Leadership se agbekale re.

Won ni, yiyan Gomina yii gegebi Gomina ti o taayo fun odun 2023 da lori awon apeere asiwaju rere ti won ri lara re papa ni akoko ti awon olugbe lpinle Oyo nilo ljoba rere.

Won ni awon ise takun – takun ti o se ni awon eka isejoba gbogbo eleyi ti o mu Idagba soke ba lpinle Oyo ko se fowo roti se yin rara.

Bakana ni iroyin fi ye wa wipe, Gomina Seyi Makinde ti gba awon Ami eye lorisirisi lati gboriyin fun gegebi Gomina ti o lami – laka, ti o si nife awon ara – ilu, ti lnu awon olugbe lpinle Oyo si dun si gidi – gidi.

 

Leave a Reply

Back To Top