FAMUYIWA WARNS TRADERS TO DESIST FROM TRADING ON THE WALKWAYS THURSDAY 30 MAY,2024
Following series of reports concerning menace of traders displaying there goods on walkways putting pedestrians on harm’s way The Council Chairman of Agbado/Oke-Odo LCDA, Hon. David Oladapo Famuyiwa has warned traders trading on walk ways of major roads within the LCDA to desist from or face the wrath of the law. Famuyiwa who spoke through […]
Ajo ICPC Ti Ro Awon Omo Orile-ede Naijiria Lati Faa Oju Ro Si Iwa Ajebanu (Iroyin Itanilolobo) Monday,11 December 2023
Ajo olominira ti o n gbogun ti iwa ibaje ati awon kudie kudie miran iyen independent corrupt practices and other related offenses commission (ICPC) ni o ti ro omo orilede Naijiria lati se ara won lokan fi owo sowopo gbogun ti iwa ajebanu owo ilu bi o ti je wipe o je ohun kan ti […]
Gomina Seyi Makinde Gba Aami Eye Gegebi Gomina ti To Taayo Fun Odun 2023(Iroyin Itanilolobo) Monday,11 December 2023
Gomina lpinle Oyo, onimo – ero Seyi Makinde ni Iroyin fi lede wipe, o ti gba aami – eye gegebi Gomina ti o lamilaka fun odun 2023. Iroyin fi ye wa wipe, loni ojo kokanla osu kejila odun ti awa yii, gomina meta ti won yan kakakiri orile – ede yii, ti won si Yan […]
Oluso-aguntan Adewale Giwa Ti Ro Aare Bola Tinubu (Iroyin Itanilolobo) Monday,11 December 2023
Latari ldibo gomina ti yio waye ni ipinle Ondo ni odun 2024, olusoagutan kan, Adewale Giwa ti gba Aare Bola Tinubu ni imoran lati ma yan enikeni lori awon olugbe lpinle naa Oro yii lo waye ni ibi lpade adura ti oluso – agutan se agbekale re fun gomina Rotimi Akeredolu lana ode yii. Oluuso- […]
Gomina Ipinle Ogun Ti Ro Awon Adari Esin Jake-jado Lati Tepelemo Ojuse Won(Iroyin Itanilolobo) Monday,04 December,2023
Gomina ipinle Ogun, omoba Dapo Abiodun ni o ti roo awon adari esin jake jado lati tepele mo ojuse won lati mu iyanju ba awon ohun ti orile-ede yii dojuko ni akoko yii. Gomina lo so eyi ni ibi ifilole awon oloye titun kan ti o waye ni ijo The Apostolic church, Nigeria ni ipile […]
Ajo ASUU Eka Ti Ipinle Bauchi Ti Roo Ijoba Apapo Lori Eyawo Ti Won Seto Fun Awon Akeko Ile Eko Giga (Iroyin Itanilolobo) Monday,04 December,2023
Ajo awon osise Ile eko giga ti a mo si Academic staff union of universities (ASUU) eka ti ipinle Bauchi ti n fon rere re bayi wipe, awon Omo Ile eko giga ko nilo eyawo ni akoko ti won wa ni ile eko,bikose ki ijoba o se eto Owo iranwo fun won. Eniti o je […]
Akowe Agba Fun Ijoba Apapo Ti So Di Wipe Oun Ni Idaniloju Wipe Ojo Ola Orile-ede Naijiria Yio Dara(Iroyin Itanilolobo) Monday,04 December,2023
Eniti o je akowe fun ijoba apapo Orile-ede Naijiria, George Akume ni ti fi lede bayi wipe, oun ni idaniloju wipe ojo ola orilede yii yio dara ati wipe ki awon Omo Orile-ede yii maa so ireti nu ninu isejoba orile ede Naijiria Akume lo soro idaniloju yii ni ibi ipade adura at iyin kan […]
Ijoba Apapo Ti So Fun Ile Isé Epo Chevron Lati Yanju Aawo Ti O Wa Laarin Won Ati Awon Agbegbe Ti Won Tedo Si(Iroyin Akoyawo). Thursday,30 November,2023
Ijoba apapo ti pase fun ile isé epo ti Chevron lati yanju aawo ti o wa laarin ile isé naa ati awon agbegbe ti won tedo si ni ilu Warri ni ipinle Delta ,ni ibi ti a ti ri awon adugbo bii, Igbororo,Igbegungun,ati Denbele ni ijoba ibile Guusu ilu Warri latari oruko ti won fe […]
Ajo CDPC Ati WHO Pelu Ajo Elero Ilera Ti UK Ti Gbimo Po Lati Se Ifilole Eto Ilera(Iroyin Akoyawo) Thursday,30 November 2023
Ajo ti o risi oro igbogun ti itankale aarun center for disease control and prevention ati world health organization WHO ti o je ajo eleto ilera agbaye pelu ajo eleto ilera ti orile-ede United Kingdom ti gbimo po bayi lati se ifilole eto ilera, eyiti yoo le ma sé kokari fun awon eniyan ti o […]
Aare Bola Tinubu Ni Iroyin Ti Fi Lede Wipe O Ti Ye Pepe Owo Ti O To Trillionu Metadinlogbon Ati Aabo Naira (Iroyin Itanilolobo) Monday,30 November,2023
Aare Bola Tinubu ni Iroyin ti Fi lede bayi wipe o ti te pepe Owo ti o to trillionu metadinlogbon ati aabo Owo naira(27.5trillion) gegebi Owo isuna fun odun 2024 siwaju awon omo ile igbimo asofin lana ode yii ti o je ojo kokandinlogbon osu kokanla odun 2023. Gegebi eni ti o je onimoran si […]