De-Genius Olivet College Tún Ti Peregedé Nínú Ìdíje JETS Àti STAN Nílùú Abuja
Ile eko De Genius Olivet College to wá n’ilu Ota, Ìpínlẹ̀ Ogun niroyin ti fi lede bayi wipe o lewaju laarin awon ile eko to to gbangba sun loye lorileede Naijiria lawon to kopa ninu idije ifigagbaga lori imo,ti egbe awon ojewewe nile eko girama ti won n kọ́ nipa imo ero ati ijinle sayensi. […]
Ilé Ẹ̀kọ́ De Genius Olivet College Tayọ Nínú Ìdíje Ẹgbẹ́ JETS
Ile eko De Genius Olivet College to wa nilu Ota nipinle Ogun ni won ti jawe olubori bayii ninu ifigagbaga awon akeko to wa ninu egbe Junior Engineers Technicians and Scientists Contest (JETS) iyen eko Imoju-ero ati Ijinle Sayensi laarin awon akeko nile eko giga jakejado ipinle Ogun. Ifagagbaga yii lo wáyé l’Ojobo ti o […]
Ayẹyẹ Ìsìn Ìdúpẹ́ ọdún kẹẹ̀dógún fún ìrántí ìyá wa Olóògbé Snr Mother In Israel Adedoyin Iyabode Sobo
Ayẹyẹ Ìsìn Ìdúpẹ́ ọdún kẹẹ̀dógún fún ìrántí ìyá wa Olóògbé Snr Mother In Israel Adedoyin Iyabode Sobo (Nee Adams )tó wáyé ní ọjọ́ Àìkú tó jẹ́ ọjọ́ kejilelogun oṣù kẹsàn-án ọdún 2024 tí a wà yìí nínú gbọ̀ngàn ilé ìjọsìn Sacred Cherubim And Seraphim El-Bethel Shiloh Cathedral tó wà ní 68,Ipaja Road ,Oke Kòtò Agege […]
Àjọ Lagos Mega Youth Festival Ṣe Àjọyọ̀ Asiwaju Bola Ahmed Tinubu
Ọjọ́ Ẹtì tí ó jẹ́ ọgbọ́n ọjọ́ oṣù kẹjọ tí a wà yìí ni àjọ kan tí ó ń ṣe Kóríyá fún àwọn Ọ̀dọ́ ní Ìpínlẹ̀ Èkó ,Lagos Mega Youth tẹ pẹpẹ ayẹyẹ ìmọrírì Ààrẹ Orílẹ̀ èdè yìí ,Asiwaju Bola Ahmed Tinubu . Ayẹyẹ yìí tí ó wáyé ní agbègbè Abúlé Ẹ̀gbá ní Ìpínlẹ̀ Èkó […]
Wọn Tí Ṣe Kìlọ̀-Kìlọ̀ Fún Àwọn Ọlọ́jà Láti Dẹ́kun Ìpàtẹ Sójú Ọ̀nà Lágbègbè Agbado Òkè-Odò LCDA
Lẹ́yìn onírúurú ìkìlọ̀ tí wọ́n ti ṣe fún àwọn ọlọ́jà tí wọ́n máa ń pàtẹ ọjà wọn sí ojú ọ̀nà tí àwọn ẹlẹ̀sẹ̀ ń rìn lágbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ìdàgbàsókè Agbado Òkè odò LCDA. Èyí náà ló mú kí alága ìjọba ìbílẹ̀ ìdàgbàsókè yìí, Hon. David Oladapo Famuyiwa wá ṣe kìlọ̀-kìlọ̀ fún àwọn ọlọ́jà láti dẹ́kún […]
Ayẹyẹ Ìgbàyọ̀ǹda Ṣeun Ọmọ́le Ní Ilé Iṣẹ́ Rédíò Ìràwọ̀ 92.1 fm.
Ọjọ́ Àbámẹ́ta Satide, Ọjọ́ keedogbon osu karun odun 2024 ni Oluwaseun Omole ti o je okan lara awon ti o n kẹ́kọ̀ọ́ nipa imo ise ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ gba ìyọ̀nda nile iṣẹ́ Radio Irawo 92.1Fm leyin ti awon alase ti buwolu pe o ti peregede, o fi gbọ̀ọ̀rọ̀ jẹkà nibi ise naa. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ awon èèyàn tó peju […]
Ajo ICPC Ti Ro Awon Omo Orile-ede Naijiria Lati Faa Oju Ro Si Iwa Ajebanu (Iroyin Itanilolobo) Monday,11 December 2023
Ajo olominira ti o n gbogun ti iwa ibaje ati awon kudie kudie miran iyen independent corrupt practices and other related offenses commission (ICPC) ni o ti ro omo orilede Naijiria lati se ara won lokan fi owo sowopo gbogun ti iwa ajebanu owo ilu bi o ti je wipe o je ohun kan ti […]
Gomina Seyi Makinde Gba Aami Eye Gegebi Gomina ti To Taayo Fun Odun 2023(Iroyin Itanilolobo) Monday,11 December 2023
Gomina lpinle Oyo, onimo – ero Seyi Makinde ni Iroyin fi lede wipe, o ti gba aami – eye gegebi Gomina ti o lamilaka fun odun 2023. Iroyin fi ye wa wipe, loni ojo kokanla osu kejila odun ti awa yii, gomina meta ti won yan kakakiri orile – ede yii, ti won si Yan […]
Oluso-aguntan Adewale Giwa Ti Ro Aare Bola Tinubu (Iroyin Itanilolobo) Monday,11 December 2023
Latari ldibo gomina ti yio waye ni ipinle Ondo ni odun 2024, olusoagutan kan, Adewale Giwa ti gba Aare Bola Tinubu ni imoran lati ma yan enikeni lori awon olugbe lpinle naa Oro yii lo waye ni ibi lpade adura ti oluso – agutan se agbekale re fun gomina Rotimi Akeredolu lana ode yii. Oluuso- […]
Gomina Ipinle Ogun Ti Ro Awon Adari Esin Jake-jado Lati Tepelemo Ojuse Won(Iroyin Itanilolobo) Monday,04 December,2023
Gomina ipinle Ogun, omoba Dapo Abiodun ni o ti roo awon adari esin jake jado lati tepele mo ojuse won lati mu iyanju ba awon ohun ti orile-ede yii dojuko ni akoko yii. Gomina lo so eyi ni ibi ifilole awon oloye titun kan ti o waye ni ijo The Apostolic church, Nigeria ni ipile […]