Close sidebar

Oluso-aguntan Adewale Giwa Ti Ro Aare Bola Tinubu (Iroyin Itanilolobo) Monday,11 December 2023

Latari ldibo gomina ti yio waye ni ipinle Ondo ni odun 2024, olusoagutan kan, Adewale Giwa ti gba Aare Bola Tinubu ni imoran lati ma yan enikeni lori awon olugbe lpinle naa

Oro yii lo waye ni ibi lpade adura ti oluso – agutan se agbekale re fun gomina Rotimi Akeredolu lana ode yii.

Oluuso- Agutan Giwa ro Aare Tinubu lati fi aaye sile fun awon olugbe lpinle Ondo lati yan enikeni ti won ba Fe, o ni ki Aare maa si gbiyanju lati faa enikeni kale bi o ti se seyin, leyi ti o sokunfa opolopo rogbodiyan ti o n sele lowo – lowo ni ipinle naa

o ni nigbati gomina Akeredolu nlo ni saa keji, oun fi lede wipe, ko si oun kan pato ti isejoba elekeji re yii le mu ba awon olugbe lpinle Ondo, o wa ro awon olugbe ipinle naa lati dibo yan enikeni ti won baa Fe nigbati o ba to akoko ldibo naa.

Leave a Reply

Back To Top